Brymo – Okunrin Meta (Edun Okan) Lyrics

Brymo – Okunrin Meta (Edun Okan) Lyrics. Gbemi san le
Ko mi sita
Fami lewu ya
Temi lorun pa
Eniyan lasan ni mo je
Mo fuye bi paper
Iji ja lodo
O gbemi lo soko
Edun Okan
Ohun lokan
Gbemi lo sibi tokan
Oga ta Oga o ta
Olopa gba riba kasa
Full Lyrics : Brymo – Okunrin Meta (Edun Okan) Lyrics